Ìdándè na a ti o ga jùlo

Ìdándè na a ti o ga jùlo

Akotan

O le dabi ẹnipe ijiya yo o ma a tẹsiwaju titi lai, ṣugbọn Jesu Kristi Oluwa sọ wi pe yo o dopin l'ọjọ kan. O ṣe ileri lati pada wa si aye yi i lati ko awọn eniyan Rẹ lọ si ibi ti a n pe ni "Ijọba Ọrun." Ni ibi agbayanu yi i, ko si ibanujẹ, ko si iku, bẹ ẹ si ni ko si itunnibi lehin ti a ba ku tan. Ao ma a gbé titi lai pẹlu Ọlọrun Ẹlẹda a! Iwe-ilewọ yi i sọ fun wa nipa bi a ti ṣe le mura silẹ fun itusilẹ wa ikẹyin.

Danloodu

Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa

Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!

newsletter-cover