Fifa ohun to dara ninu iponju

Fifa ohun to dara ninu iponju

Akotan

Ọpọ awọn eniyan loni i ni wọn n jiya ihuwasi lona odi ati aṣilo. Jesu gbe igbe aye ijiya pẹlu. O ran awọn miiran lọwọ, O wo wọn san, O si kọ wọn ni ọna ti o dara ju. Awọn eniyan kan korira Rẹ wọn si pa a, ṣugbọn lẹyin ọjọ kẹta, O ji dide O si pada si ọdọ Baba Rẹ ni ọrun. Iwe-ilewọ yi i ṣe atunsọ die niti igbe aye ati ijiya ti Jesu ni ṣoki, ati ileri Rẹ lati wo ọkan wa ti o gbọgbẹ san pẹlu.

Danloodu

Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa

Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!

newsletter-cover