Idajọ fun ohun ti o n dun Mi

Idajọ fun ohun ti o n dun Mi

Akotan

Ijiya kì yo o wa titi lai. Iwe ilewọ yi i sọ nipa ẹni ti o jiya ifipabanilo kan bi o ti n ṣe ijiroro nipa idajọ ikẹhin ti Ọlọrun Ẹlẹda a yo o ṣe fun awọn eniyan buburu. O ṣ'alaye bi Jesu ṣe bu ẹnu àtẹ́ lu awọn adari alagabagebe ti O si ṣe ileri idajọ ti yo o ṣe idalare fun awọn ti wọn ti o ti jiya. Ṣugbọn bi awa funra wa ba ti ṣina, ọ̀nà wa pẹlu ti a fi le dariji wa nipasẹ ijiya ti Jesu Kristi Oluwa ti farada fun wa.

Tẹ̀

Tract

Òǹtẹ̀wé

Sharing Hope Publications

A le è ri ní

5 Àwọn èdè

Àwọn Ojú-ewé

6

Danloodu

Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa

Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!

newsletter-cover