Aabo kuro lọwọ awọn Ẹ̀mí Buburu

Aabo kuro lọwọ awọn Ẹ̀mí Buburu

Akotan

Awọn ẹmi buburu wa nitootọ, wọn si le banilẹru jọjọ. Awọn eniyan kan sọ wi pe awọn ni agbara lori awọn ẹmi naa, ṣugbọn wọn n gba owo ki wọn to le ran wa lọwọ. Jesu Kristi ni agbara lati dè ati lati lé awọn ẹmi àìmọ́ jade, ṣugbọn ko ni beere fun sisan owo. O ma a n ran awọn eniyan lọwọ lọfẹ ẹ nitori pe O kun fun aanu ati nitori pe Oun, pẹlu, korira lati ri ki awọn ẹmi buburu ma a hale mọ wa. Ìwé-ilewọ yi i sọ fun wa nipa ibi ti ẹmi buburu ti wá ati bi a ti ṣe le gbadura si Jesu fun itusilẹ kuro lọwọ awọn ẹmi àìmọ́.

Danloodu

Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa

Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!

newsletter-cover