Ṣé Jesu le è ṣe iranwọ bi?
Akotan
Gbogbo wa ni a n koju awọn iṣoro ninu igbesi aye wa eyi ti a ko le danikan yanju. Ni igba miran a ma a n ro wi pe ko si ẹni ti o ri irora wa, ṣugbọn Ọlọrun Ẹlẹda mọ ohun gbogbo nipa rẹ. O ran Ọmọ Rẹ, Jesu, pẹlu eto lati ran wa lọwọ lati bọ kuro ninu ijiya patapata. Awọn itan mẹta wọnyi ṣe alaye nipa awọn eniyan ti wọn ni wahala ti wọn si yi oju si Jesu fun iranlọwọ. Ko si eyikeyi ninu wọn ti o mọ Jesu daradara ni akoko na a, ṣugbọn lẹyin ti O ran wọn lọwọ tan, wọn fẹ mọ Ọ daradara si I. Iwe-ilewọ yi i kọ wa nipa bi a ti ṣe le gbadura ki a ba a le sọ fun Jesu nipa awọn iṣoro wa. Yo O ran wa lọwọ, pẹlu!
Tẹ̀
Tract
Òǹtẹ̀wé
Sharing Hope Publications
A le è ri ní
12 Àwọn èdè
Àwọn Ojú-ewé
6
Danloodu
Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa
Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!
Wá Àwọn Olugbọ ọ Rẹ
Awọn atẹjade ti o fi ara han
© 2024 Sharing Hope Publications