Ọjọ Iwaju ti o Dara Ju

Ọjọ Iwaju ti o Dara Ju

Akotan

Ninu aye yi i, awọn ohun buburu ma a n ṣẹlẹ. Awọn eniyan n jiya, wọn si n ku. Ṣugbọn ireti wa fun ọjọ iwaju! Iwe mimọ ti awọn Kristẹni, Bibeli, wi pe Jesu n bọ lati mu awọn eniyan ti wọn fẹran Rẹ lọ si ibi ti o dara. Nibẹ, ko si ẹni ti yo o ṣaisan tabi jiya. Gbogbo eniyan ni yo o ma a gbe ni alaafia ati ni irẹpọ titi lai. Iwe ilewọ yi i sọ fun wa nipa bi a ṣe le kopa ninu ọjọ iwaju ti o rẹwa ti Ọlọrun ni ni ipamọ!

Danloodu

Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa

Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!

newsletter-cover