Awọn Eniyan pataki Ọlọrun

Awọn Eniyan pataki Ọlọrun

Akotan

Jesu Kristi Oluwa sọ fun wa nipa bi yo o ti ṣe tun aye ti o pe da ni aye ti nbo. Awọn eniyan Rẹ pataki yo o gbe nibẹ titi lai. Awọn wo ni awọn eniyan pataki wọnyi? Bibeli pe wọn ni "aṣẹ́kù." Iwe-ilewọ yi i ṣe alaye ranpẹ nipa awọn aṣẹku, o si tun sọ fun wa nipa iṣẹlẹ ti gbogbo wọn n fi itara wọna lati ri.

Danloodu

Fi orúkọ sílẹ̀ fun awọn ìwé-ìròyìn wa

Jẹ́ ẹni akọkọ ti yo o mọ igba ti awọn atẹjade tuntun bá ti jade!

newsletter-cover